Ile Martial ti daru o


image

Iyawo re lo ko sile.

Nitori o ba Mikel Oyarzabal, sun ni osu kini odun yi.

Ja fun ori ara re ni EPL, ja fun oko re ni fun awon ti won n gba boolu nibe.

Advertisements

Atileyin wa ose yi


Ogbeni Giovanni, atileyin Arsenal ni won bori ibo ose yi.

Yato si wipe won ma je aworan wa, won ma gba ebun airtime kekere kan.

E ku oriire na.

Ki eni ti o fi aworan na ranse ba mi soro fun ebun won.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

E wo eni ti o n so bombu si awon papa Europe


image

Idi ni wipe won ri arakurin yi, Salah Abdeslam, ni agbegbe ori papa ti won ti fe gba boolu na.

Salah Abdeslam je okan lara awon ti o wa nidi isele Paris na.

Hmm.. Ki Eledumare so wa o.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba