Kobe ku ise


image

O fi boolu alapere le lano.

Hmmm… o gbiyanju to fun Lakers, o si so wipe o wu ohun lati tesiwaju sugbon ara ohun ni ko je.

Advertisements

Pele fe gba ipo Neymar


image

Nkan kan pere ti Brazil ko I ti gba ni ipo kini ni Olympics.

Pele so wipe o wu ohun lokan lati gba.

Nitori eyi, ohun ma a ma gbaradi lati ri wipe Dunga mu ohun na.

Pacquiao feyinti


image

O na Bradley ni ija ti o so wipe ohun ma ja keyin ni igbesi aye re.

Ohun na ti feyinti bi Mayweather… Ese ti ba won lori daada.

Ti won ba ri owo gidi, won ma ja si o.

Ibo ni Mourinho ma wa ni sa to n bo?


image

“Mo le fi da yin loju wipe mo ma darapo mo egbe agbaboolu kan ni opin sa yi.

“Mi ko le daruko re bayi nitori won po ti won fe mi, sugbon ki sa yi to pari, ma a mu ikan, ara mi gan ti wa lona.

“Egbe ti o ba feran mi ju ni mo ma tele,mi ko de fe league ti o ba rorun rara.”

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba