Fifa mu inu wa dun o


image

Laipe, a ma pada ri awon alayo bi Zidane, Ronaldinho, Carlos, Beckham Okocha ati awon alayo ti won ko ba i ti ju odun marundinlaadota lori papa

Odun 2017 ni a ma duro de bayi ki World Cup fun awon Agbalagba na bere ni Mexico.

Orile ede mejila ni won fe fi bere.

Odun meji meji si ni won ma fi ma gba a.

Inu mi dun gan si iroyin yi o.

Bi Ronaldo ati Messi feyinti gan, a si ma ri won daada.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Advertisements

Fifa ko ba gbo’ro si wa lenu


image

Fifa ti pinu lati ma yi enu pada lori oro World Cup Qatar 2022.

Won ti pariwo titi wipe ko gbodo waye niwon igba ti osu kokanla nikan ni won ma ti le e gba.

Ojo kokanlelogun osu kokanla odun 2022 ni won ma bere si ni gba ni Qatar, won si ma gba fun ojo mejidinlogun, yato si ojo mejilelogbon ti won ma fi n gba idije na tele.

Ki Eledumare da emi Blatter na si ju’gba yen lo o.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Awon ti won ti n ba Barca to iya le ni Japan.


image

Barca ma ko soju Europe ninu idije Club world cup ti o ma sele ni Yokohama ni osu kejila odun yi.

Club America lati orile ede Mexico ni won ma koko koju.

Igba wo ni Africa ma tu gba ife eye yi o?

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Tani o tu gba World Cup bayi?


image

Abolade Olajuwon Ryan

A dupe fun opin World Cup awon obirin to waye laarin Japan ati USA to na Nigeria ni ami ayo kan si odo.

Won koya fun Japan lati gba ife eye na. Ami ayo marun si meji ni won fi je Japan ni’ya.

Tani o fe gba ife eye na tele? USA na ni ke. Lloyd, ogagun won gba meta wole, ikan ninu re je lati aarin ori papa gangan.

USA ku oriire eleeketa. Ko ba dara, ti awon okurin won na ba gunrege bayi o.

Ese ti kika.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Olootu Sports in Yoruba re e o!


image

Abolade Olajuwon Ryan re e, tani o mo o ri?

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Ronaldo gba Ballon d’Or siwaju Messi ati Neuer


Abolade Olajuwon Ryan

Ronaldo ti gba Ballon d’Or eleeketa re, siwaju Messi ati Neuer. “Mo fe dupe lowo awon ebi mi ati gbogbo awon ti won dibo fun mi, inu mi dun gan.”

Ronaldo ni alayo keje to ma gba ife eye yi lera leyin Johan Cruyff, Kevin Keegan, Karl-
Heinz Rummenigge, Michel Platini, Marco van Basten ati Messi.

Se ife eye yi to si sa?

Enikeni ti o ba ni ounka tabi aroko yoruba le kan si wa o.
BBM : 28A99F82
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan siwa ni
sportsinyoruba@gmail.com.
iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa lori http://
http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://
http://www.twitter.com/sportsinyoruba.

Real Madrid, olori oko agbaye!


Abolade Olajuwon Ryan

Oh eh…oh eh oh eh oh eh…oh eh.. Oh eh!… Orin ti mo gbo ti awon alayo Real Madrid ko l’ale yi niyen.

Awon wo ni won ma n gba Club World Cup yi na? Awon ti won ba gba Champions League ni Europe, Africa, Asia, South America ati North America ni. Sugbon, aarin awon to gba Champions League Europe ati South America ti a n pe ni Copa Libertadores ni ija ife eye na ma n saba wa. Awon ti South America ti gba a ni igba merin nigba ti awon ti Europe ti gba a ni emeje bayi.

Real Madrid lo gba ikeje, ope lowo olori oko bambam ti o n fi ori gba awon ami ayo wole, ogbeni Sergio Ramos. Ifesewonse Semi Final, ohun na ni o si ate ami ayo bi o se fi ori gbe ayo na wole. Abajo ti won fi fun ni boolu wura fun alayo to se daadaa ji ninu idije na siwaju Cristiano Ronaldo to gba boolu fadaka.

Ife eye keji ti Madrid ma gba ni sa yi re e leyin European Super Cup ti won na Sevilla gba. Aseyori nla re e nitori Real Madrid ko gba ife eye yi ri lati igba ti won ti n pe ni Club World Cup sugbon won gba meta nigba won pe ni Intercontinental Cup.

Real Madrid na Lorenzo ni ami ayo meji si odo, Aukland si gba ipo keta lowo Azul Cruz.

Eyin atileyin Real Madrid, eku oriire o, oriire ni Madrid fi pari 2014… Hala Madrid.

Ese ti kika.

Enikeni ti o ba ni ounka tabi aroko yoruba le kan si wa o.
BBM : 28A99F82
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan siwa ni
sportsinyoruba@gmail.com.
iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa lori http://
http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://
http://www.twitter.com/sportsinyoruba.

Se o ye ki won fun Messi ni boolu goolu? – Neymar


Abolade Olajuwon Ryan

“Ni akoko, atileyin Messi ni emi, mo feran re gan, o si wa lara awon ti won se daadaa ju ni World Cup.

Messi, omo orile ede Brazil ti won kan leyin ni o n so oro yi fun wa. “Schweny ati Robben na wa lara awon ti won se daadaa ju ni Brazil.

Oro ti gbogbo eyan n so nipa boya o ye ki won fun Messi ni ife eye goolu ni Neymar nso.

“Nitemi o, Messi sa wa lara awon meta to se daadaa ju ni Brazil sugbon mi o le so boya o se dara ju Robben ati Schweinsteiger lo.

“Eni ti o ba gbaradi ju lo ma n jawe olubori ni boolu ni won fi na Brazil jabo jare, ti a ba gbaradi daada, a ma gba World Cup sugbon Germany ati Spain gan dara ju wa lo bayi.” Ni Neymar fi pari oro re.

Ese ti kika.

E jowo, ema gbagbe lati feran wa lori http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba. Fun ipolowo, imoran tabi isina, e le kan siwa ni sportsinyoruba@gmail.com. e ku ife.

O ye ke gbe Suarez lo si YABA APA OSI- aare Uruguay


Abolade Olajuwon Ryan

“Mo mo wipe o ye ki won fi iya je Suarez, sugbon iya ti FIFA fi je yi ti poju” ni oro ti o jade lenu aare Uruguay lano.

Jose Mujica tu so wipe nitori Suarez ko lo si ile iwe na ni FIFA se n se bayi.

“Suarez ti lo si Barca nisin, sugbon a ko mo igba ti o ma to gba boolu.

“Eleyi ti FIFA ni ki o ma gba boolu fun osu merin yen, o ye ki won ran lo si ile iwosan alarun opolo ni, ki ni o wa se to to yen?”

“Ori awon FIFA yi gan ko sise rara, nitori arugbo ti poju laarin won” ni Mujica ti o je aare to tosi ju ni agbaye so.

Ese ti kika.

Spain ati Germany dara ju Brazil lo- Neymar


Abolade Olajuwon Ryan

Omo Barca ti Zuniga se egungun re ni World Cup, Neymar Jr, ti so idi ti Brazil ko se ri owo mu ni World Cup to koja yi.

“Ti e ba lo si Spain ti mo ti n gba boolu, e ma ri wipe won mu igbaradi won ni pataki ni, won ko fi sere rara.

Gbogbo wa la si mo wipe igbaradi gangan ni awon alayo ti ma n leko ju.

“Amoo ni Brazil, ah! Won ko mu igbaradi won ni koko rara.

“Awon irinse ti a n lo ni Barca no ni Spain ati Germany n lo, nitori re ni won se dara ju wa lo.

“Ti enikeni ko ba le so otito fun Brazil, emi ma so” ni Neymar so ninu ipalara eyin re.

Ese ti kika.

E jowo, e ma gbagbe lati feran wa lori facebook @ http://www.facebook.com/sportsinyoruba, e si le tele wa lori twitter @ http://www.twitter.com/sportsinyoruba. Fun ipolowo, imoran ati isina, e le kan siwa ni sportsinyoruba@gmail.com. ese gan, eku ife.