Tani o fe ra AC Milan


image

Arakurin yi lati China ti setan lati San gbese won, ati lati ra egbe na pa pelu milionu ogorun meje pon.

Advertisements

Se won fi siga se alayo yi ni?


image

Roma ko lati lo arakurin yi ni ano, a gbo wipe won fi iya je ni nitori siga ti won tu ba lowo re.

Fun awon ti ko ba mo, arakurin yi fa ina ju Sango lo.. ~~=[ ~~=[ ~~=[ ~~=[ ~~=[ *run* *run*

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba