Nkan ti Ronaldo n je fun Man City


image

Ounje re gan, o n je opolopo nkan ti o ma tete je ki o pada

Advertisements

Awon ti won fe pa Madrid po o


image

“Mi ko fe koju Real Madrid nitori oju ti ma n wa lara boolu Champions league ti egbe meji lati Spain ba fe pade sugbon o wu mi lati gbesan nkan ti o sele ni odun meji seyin lowo won.”

Atletico fe gbesan, Bayern na fe gbesan, koda Man City na fe gbesan lara Madrid..