Terry jewo eni ti o fun ni wahala ju


image

“Thierry Henry ni o, aramanda alayo ni arakurin yen.”

Won wa bere lowo re wipe tani alayo wo ni o feran ju lati ma gba eyin pelu re?

“Ni Chelsea, Carvalho ni o, ni England, Ferdinand.”

Advertisements

Ibo ni Mourinho ma wa ni sa to n bo?


image

“Mo le fi da yin loju wipe mo ma darapo mo egbe agbaboolu kan ni opin sa yi.

“Mi ko le daruko re bayi nitori won po ti won fe mi, sugbon ki sa yi to pari, ma a mu ikan, ara mi gan ti wa lona.

“Egbe ti o ba feran mi ju ni mo ma tele,mi ko de fe league ti o ba rorun rara.”

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Tani o n tan Guardiola?


image

Jan Kirchhoff, alayo Bayern tele to wa ni Sunderland bayi so wipe “O ma rorun fun Guardiola lati gba EPL.

“Koda, ko ni lera rara. O ma yi EPL pada gan ni, awon ti won wa ni City ma gbadun ise re gidi gan ni.”