Dalung soro si Pinnick

image

Minista fun eto idara, Dalung ti da si oro boolu Nigeria.

Awon ti o n ta lara bi Nigeria se padanu AFCON 2017 gbe patako ti won si ko si wipe ki o fi ipo na sile.

Pinnick so wipe ohun ko ni fi ipo aare NFF na sile leyin igba ti ile ejo kan ni Jos tu le danu.

Dalung wa so wipe “ogbeni Pinnick, o ti e mo oro so rara, ki i se gbogbo oro ti won ba so si e ni o gbodo fi esi si. O n ba ara’e je ni o.

Advertisements

Ha! Nigeria yi sa

image

A ko si lara awon orile ede mewa ti o dangajia ju ni Africa gan lowo yi.

Ipo kerindinlaadorin la wa ni agbaye, a si wa ni ipo kerinla ni Africa.

Eleyi ko dara rara o

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Nigeria ku oriire

image

Adupe gidi gan ni lowo Eledumare fun aseyori awon odo omode wa U17 ti won gbesan lowo Mali lati gbe ife eye Fifa World Cup.

Ki won ma gbagbe won o.

Nigeria gba ife eye yi nigba ti Buhari je aare tele, won tu ti se bayi.

Igba otun re e o.

Gbosa meje fun won!

Adupe lowo Eledumare.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Ogbon ti Nwakali ko gbogbo omo Nigeria

image

Ti won ba ja wa kule ni ibi kan, o ye ki a te’pa mo’se ni o.

Ogagun U17 wa, Nwakali wa lara awon ti Manu Garba fe ko lo UAE ni 2013, sugbon won ja kule.

Ko so’reti nu, o pada wa di eni ti o se asiwaju gbe ife eye na.

Yato si iyen, o tu gba golden ball, ko tu tan sibe o, o gba Adidas bronze boot.

Victor Osimhen gba Adidas golden ball fun ami ayo mewa, ko si eni ti o se iru re ri.

Up Eaglets.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Nigeria ti n sumo Rwanda o

image

Ninu igbaradi CHAN ti o n bo laipe ni Rwanda lodun to n bo, Nigeria bori Burkina Faso lori papa Adokiye Amiesiamaka Stadium, Port Harcourt.

Bature Yaro ati Gbolahan Salami ni won gba ami ayo kan kan wole fun Nigeria.

Nigeria ku oriire o.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Nigeria ti bere daada o

image

Adupe wipe a ti bere U-17 wa daada ni Chile bi a se na USA ni ami ayo meji si odo.

Ami ayo meji ni abala keji lati owo OSIMHEN ati
AGOR ni a fi bori won.

Koda, omo Nigeria kan gba boolu fun USA. Olosunde Matthew ni oruko re.

Se a gba boolu na daada?

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Kini Nigeria ma ti se eleyi si bayi?

image

Bi Oliseh se gba ipo ogagun lowo Enyeama ati wahala ti o wa laarin awon mejeeji, Vincent ti ko Nigeria sile bayi.

“Odun metala ni mo ti lo pelu Nigeria, ko si igba ti mi ko fi inu kan ba orile ede mi lo” ni Enyeama so.

“Eledumare nikan ni o le san ni esan ire fun nkan ti mo se fun Nigeria.

“O digba o, o dabo, ki Olorun so ipade wa, ise mi ti pari pelu Nigeria.”

Bawo ni e se ri eleyi ?

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Tani o ma pari ija Nigeria bayi

image

Leyin ijakadi ti o sele laarin Oliseh ati amule Enyeama nitori Enyeama pe de ago awon alayo latari oku mama re ti won lo sin, akoni moogba wa ti ropo ogagun egbe na, Enyeama fun Ahmed Musa.

Hmmm! Se o ye k’a da Oliseh lebi ni tabi Enyeama?

Se o ye ki Oliseh fa awon alayo re mo’ra ju bayi lo tabi owo ti o n gbe yi gangan ni won nilo ninu egbe na.?