Ibo ni Mourinho ma wa ni sa to n bo?

image

“Mo le fi da yin loju wipe mo ma darapo mo egbe agbaboolu kan ni opin sa yi.

“Mi ko le daruko re bayi nitori won po ti won fe mi, sugbon ki sa yi to pari, ma a mu ikan, ara mi gan ti wa lona.

“Egbe ti o ba feran mi ju ni mo ma tele,mi ko de fe league ti o ba rorun rara.”

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Advertisements

Rooney de!!!

image

Tottenham daran… *run* *run* *run* *run*

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Ferdinand bi Man Utd gan ni o

image

Alayo Man Utd tele ri yi so wipe “Man Utd gba iranu lano, won ko mo nkan ti wo n se rara.

“Liverpool gba won pa danu. O ye ki oju ti won ni.”

Se Man Utd si le tesiwaju sa?

Ki won lo pe Rashford wa.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Rooney gbe’ja Van Gaal

image

Ogagun Man Utd na so wipe ki won ye da Van Gaal lebi fun ijakule won.

Wipe “awa ti a n gba boolu na gangan ni o ye ki e da lebi. Awa ni a ko gba boolu daada to.

“Nkan ti o ye ki a boju to ni bi a se ma gba ami eye FA ati Europa.”