Won da Messi lebi o


image

Won ni Messi ti ko gba boolu daada ni o fa ijakule Barcelona bayi.

Bi o se ma n ri niyen.

Nitori ti won ba n se oriire na, Messi ni won ma so wipe o n se gbogbo re.

Advertisements