Hazard jewo ese re


image

“Nkan ti o sele ni sa yi ni wipe ara mi ko i ti da pe daada. O de se pataki ninu boolu gbigba gan.

“Nkan ti mo mo ni wipe ti mo ba se daada ni Euros, won ma tete gbagbe wipe mo gba iranu ni sa yi.”

Advertisements

Terry jewo eni ti o fun ni wahala ju


image

“Thierry Henry ni o, aramanda alayo ni arakurin yen.”

Won wa bere lowo re wipe tani alayo wo ni o feran ju lati ma gba eyin pelu re?

“Ni Chelsea, Carvalho ni o, ni England, Ferdinand.”

Chelsea ni Champions league


image

Igba wo ni won ma pada gba Champions league?

O daju wipe won ko le gba champions league ni sa to n bo nitori won ko le pari sa yi laarin awon merin to siwaju EPL.

Anfani ti won tu ni ni lati gba Champions league bi won se se ni 2013.

Bayi, o kere ju, won ma padanu champions league fun odun kan, bi Man Utd.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Ibo ni Hazard fe wa gan o


image

“Bi mi ko tie gba boolu daada, mo feran Chelsea gan, mo si fe pe ni ibe” ni Hazard so fun ChelseaTV.

Nkan ti o se so oro yi ni wipe o so fun awon oniroyin wipe ti PSG ba gbori wole, ohun ko ni sa o.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Simeone ni Chelsea


image

Won ni Chelsea ti se adehun pelu Simeone, arakurin yi siti ajo wipe ohun fe di Ferguson ni Atletico ni.

Awon kan so wipe Conte ni o fe gba ise na.