Neymar fe Pogba ni Barcelona

image

“Mo fe Pogba ni Barcelona.”

Advertisements

Neymar da ija sile laarin Brazil ati Barcelona

image

Brazil fe ki Neymar gba Copa America ati Olympics sugbon Barcelona so wipe awon ko ni gba ki o gba mejeeji.

Nitori awon ko fe ki o farapa ki sa tuntun to bere.

Eleyi ma ga o. Won ni awon ma fi iwe ranse si CBF.. Ti o n se alakoso boolu ni Brazil.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Barca n wa owo o

image

Ko ni so oruko kankan ni iwaju aso Barca ti won ba ti bere sa ti o n bo sugbon won ma pada gba oruko eyan kan.

Iye ti Qatar Airways n fun won ko to won mo, enu won ti fe.

Sugbon won so wipe o le pada je Qatar na, ti won ba fi owo kun owo won nitori won fe fi owo na tun ori papa won se ni.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Neymar tu asiri MSN

image

“Nkan ti o mu MSN ni agbara ni wipe ore timo timo ni a je, o soro gan lati di ore bi wipe south America ni a ti wa, a ko si gba boolu fun orile ede kona.

“Sugbon gbogbo re yori si rere bi a se je ore.”