Arsenal fe ra eni ti won ko le ri ra

image

Eni ti ko ba si lori igba no o ma n wo awon loju nigba ti won ko ni nkan se tele.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Advertisements

Beckham gbe leyin Wenger

image

Pelu bi awon atileyin Arsenal se n pariwo wipe ki Wenger lo, Beckham wa leyin Wenger.

O si fi han lori Instagram.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Arsenal rogo lowo Barcelona nipa Cech.

image

nitori itan re ti o fi sese bi won se koju Swansea.

Wenger si ti so wipe Ospina ma se ise to dara fun wa.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Alexis binu soro si Arsenal

image

“A ni awon alayo ti o le gba EPL fun Arsenal sugbon awon alayo yi ko ki n wu’wa bi wipe o wu won lati bori gbogbo England.

“Igba kan ni mo no wipe won wu’wa lati bori ifesewonse, igba ti won a si koju Man Utd ni. Laarin iseju melo kan, a ti gba meji wole.

“Oju eje ti Arsenal nilo niyen. Ko n se ki eyan ko lo gba boolu ki won si bori ni ami ayo kan si odo.”

Se ooto oro ni o so?