Hazard jewo ese re

image

“Nkan ti o sele ni sa yi ni wipe ara mi ko i ti da pe daada. O de se pataki ninu boolu gbigba gan.

“Nkan ti mo mo ni wipe ti mo ba se daada ni Euros, won ma tete gbagbe wipe mo gba iranu ni sa yi.”

Advertisements

Euro 2016 bere

image

Oni ni awon orile ede gbogbo ti won ma gba boolu Euro 2016 ma mo egbe ti won ma wa.

Yato si egbe merin ti tele, egbe mefa ni o ma wa bayi. Orile ede merin ni egbe kan so.

Awon orile ede na re

France, Spain, Germany, England, Portugal, Belgium
Italy, Russia, Switzerland, Austria, Croatia, Ukraine
Czech Republic, Sweden, Poland, Romania, Slovakia, Hungary
Turkey, Republic of Ireland, Iceland, W

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

By Abolade Olajuwon Ryan Posted in Euro 2016

Rooney so ala ti ohun la fun England

image

Abi ala ko ni?

O ku die ki Rooney fi di alayo to gba ami ayo wole ju fun England, koda, leyin ami ayo meta, o ma ti koja Sir Bobby Charlton.

Rooney si fe di oruko ti o mule ro ni England, latari iyen, o so wipe “lati di eyan bi Bobby Charlton, mo gbodo gba World cup, mo si ni Russia 2018 lati je ki eleyi di mimuse.”

Ki ni e ri so si eleyi?

Ninu aworan yi gan, o se bi eni eni ti o n gbe ife eye world cup na..

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

By Abolade Olajuwon Ryan Posted in Euro 2016

Bale fi agbara han Ronaldo

image

Nibi ti Ronaldo o ti le gbe Portugal re, Bale n se be fun Wales o.

odun merin seyin, won ko si ninu orile ede ogorun akoko ni agbaye nipa awon to dangajia ninu boolu gbigba sugbon bayi, ipo kesan ni won wa, koda, o seese ki won bo si ipo keji ti gbogbo nkan ba yori si rere fun won ki osu to n bo to de.