Kobe ku ise


image

O fi boolu alapere le lano.

Hmmm… o gbiyanju to fun Lakers, o si so wipe o wu ohun lati tesiwaju sugbon ara ohun ni ko je.

Advertisements

Awon ti won fe pa Madrid po o


image

“Mi ko fe koju Real Madrid nitori oju ti ma n wa lara boolu Champions league ti egbe meji lati Spain ba fe pade sugbon o wu mi lati gbesan nkan ti o sele ni odun meji seyin lowo won.”

Atletico fe gbesan, Bayern na fe gbesan, koda Man City na fe gbesan lara Madrid..