Barca n wa owo o

image

Ko ni so oruko kankan ni iwaju aso Barca ti won ba ti bere sa ti o n bo sugbon won ma pada gba oruko eyan kan.

Iye ti Qatar Airways n fun won ko to won mo, enu won ti fe.

Sugbon won so wipe o le pada je Qatar na, ti won ba fi owo kun owo won nitori won fe fi owo na tun ori papa won se ni.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Advertisements

Asiri Mourinho ati Beckham tu

image

Won ti fi han si agbaye wipe awon mejeeji ti n ba ere ife won lo.

Matilda ati Brooklyn

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Sheikh meji n ja tori boolu

image

Man City ma pade PSG.

Nasser Ghanim Al-Khelaïfi takes on Mansour bin Zayed Al Nahyan, sheikh kan lati Qatar ma doju ko sheikh omiran lati UAE.

Owo lo n soro.

Eyan kan ninu won sa ma pa egun re lote yi

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Kini Guardiola so fun awon alayo Bayern lati na Juve

image

*Pensive*Ehmmm.. ;shhHmmm hmmm.. *Shhh* ..  o so wipe ohun ma ge kini abe won ni ti won ko ba bori.

Ha! E ma so wipe emi ni mo so fun yin o….*run*

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Neymar tu asiri MSN

image

“Nkan ti o mu MSN ni agbara ni wipe ore timo timo ni a je, o soro gan lati di ore bi wipe south America ni a ti wa, a ko si gba boolu fun orile ede kona.

“Sugbon gbogbo re yori si rere bi a se je ore.”