Simeone ni Chelsea


image

Won ni Chelsea ti se adehun pelu Simeone, arakurin yi siti ajo wipe ohun fe di Ferguson ni Atletico ni.

Awon kan so wipe Conte ni o fe gba ise na.

Advertisements

Rooney gbe’ja Van Gaal


image

Ogagun Man Utd na so wipe ki won ye da Van Gaal lebi fun ijakule won.

Wipe “awa ti a n gba boolu na gangan ni o ye ki e da lebi. Awa ni a ko gba boolu daada to.

“Nkan ti o ye ki a boju to ni bi a se ma gba ami eye FA ati Europa.”

Iheanacho, ko da o


image

Mo ro wipe emi nikan ni mo ri ni sugbon Thierry Henry na ti soro nipa re wipe kilode ti awon alayo Man City ko se lo ba Iheanacho se ajoyo ami ayo re.

Se ko si irepo laarin won ni?

Tani o se akiyesi re?