Awon ti won ma padeni Copa del rey


image

Atletico ti ja danu.

Tani o ma a gba?

Advertisements

Atileyin wa ose yi


Ogbeni Giovanni, atileyin Arsenal ni won bori ibo ose yi.

Yato si wipe won ma je aworan wa, won ma gba ebun airtime kekere kan.

E ku oriire na.

Ki eni ti o fi aworan na ranse ba mi soro fun ebun won.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba