Barcelona ti ra eyan kan o


image

Robert Gonçalves lati Fluminense ni alayo akoko ti Barcelona ra.

Sugbon o, U19 won ni o ma gba boolu fun.

Omo orile ede Brazil ni.

O si ti pari idanwo awon dokita re.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Leave a comment