Madrid fe wa ija Mourinho o

image

Won ni Madrid n duro de opin sa yi lati ra ni.

Ti Mourinho ba gba ijoba man Utd, ko ni fe fi sile o.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Advertisements

Memphis o ran Man Utd ni se o

image

Bo Man Utd se n ri ijakule, Memphis lo ra rolls Royce tuntun ni.

Ko tu gbe sile nile o, o gbe wa si papa igbaradi.

Hmmm! Ako de.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Barcelona ti ra eyan kan o

image

Robert Gonçalves lati Fluminense ni alayo akoko ti Barcelona ra.

Sugbon o, U19 won ni o ma gba boolu fun.

Omo orile ede Brazil ni.

O si ti pari idanwo awon dokita re.