Gerrard pada si Liverpool

image

Arakurin yi ti pada si Liverpool lati ba won gbaradi sugbon ko daju rara wipe o ma si ba won gba boolu ki MLS to tu bere.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Advertisements

Won ti da ija le laarin Madrid ati Barcelona

image

Die die, ti Neymar ba tesiwaju bayi, ohun na ma gba Ballon d’Or.

Ohun, Ronaldo ati Messi ni won ma ja fun ife na ni osu kini odun ti o n bo.

Won tu ti ja EPL le o.*run* *run* *run*

Tani e lero wipe o ma gba a?

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Ija laarin ore meji ni Barca tele

image

Guardiola

Sampaoli

Enrique

Tani ife eye na ye?

Fun awon ti won ko mo Sampaoli, ohun ni akoni moogba Chile.

Ohun ni o ba won gba Cop a America ti won ko gba ri.

Eleyi ma le gan o ti won ko ba ki ojoro bo..*run*

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Se won fi siga se alayo yi ni?

image

Roma ko lati lo arakurin yi ni ano, a gbo wipe won fi iya je ni nitori siga ti won tu ba lowo re.

Fun awon ti ko ba mo, arakurin yi fa ina ju Sango lo.. ~~=[ ~~=[ ~~=[ ~~=[ ~~=[ *run* *run*