Eje Zidane lori papa Madrid

image

Real Madrid ti fun omo zidane, Enzo, ni igbega si egbe agba won.

Bi ko tile gba boolu to baba re, o ma wu wa lori lati ri eje zidane lori papa leekan si.

Ti Zidane ba di akoni moogba Madrid, Enzo ma raye fi ara re han daada.

Sugbon o, o jo kaka o.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Advertisements

Falcao de Russia die…

image

A gbo tele wipe Villas Boas fe gbe Radamel tele sugbon arakurin na to da si oro na.

“Ki sa yi to bere ni a ti fe gbe Falcao lati Chelsea sugbon ofin tuntun kan ni Russia ti won so wipe a ko gbodo ko ju alayo mefa sori papa ti ki i se omo orile ede Russia lo mi wa ma ra a mo.

“Baayi, a ko le ra a nitori alayo mejo ni a ni ni Zenit ti ki i se omo orile ede Russia.”

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Aare Barca salaye bi Neymar se ma kuro ni Barca

image

Gege bi iroyin ti a gbo lati enu aare Barcelona tele, Joan Laporta, Inter Milan ko owo tabua le lati ra Messi nigba ti ohun si je aare Barca sugbon ohun ko ni.

A n gbo wipe Messi fe fi Barcelona sile nitori wahala ti awon olowo ori Spain n fun.

Laporta wa so wipe “e gbagbe iyen, Messi ko le kuro ni Barca lai lai”, se ohun je Olorun ni =]y ?

“Sugbon o, o seese ki Neymar kuro ni Barca laipe”

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Ramires 2019

image

Alayo Chelsea yi to wa lati Brazil ti ba egbe re se adehun tuntun.

Leyin odun marun ti Ramires ti lo, 2010 ni Chelsea ra lati benfica, adehun odun merin tuntun ni won wa se bayi.

“Lati igba ti mo ti de, a ti gba gbogbo ife eye ti o seese, inu mi si dun si. Odun merin to ku yi, ki Eledumare ran wa lowo lati gba opolopo si i” ni Rami so.

2019 ni adehun tuntun yi ma pari.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Leyin Chelsea, ibi ti Mourinho n lo re e

image

Looto ni wipe a n gbo seti bi PSG ati Inter se fe gbe arakurin yi.

Sugbon, eyi to daju ju, ti a n gbo bayi ni wipe oro ti n lo lowo laarin Mourinho ati Monaco.