La liga na ti subu lona o

image

Bi Benfica se na Atletico Madrid.  =]y ..

champions league niyen o.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Advertisements

Ronaldo yaju si agbalagba

image

Nitori lowo yi, Ronaldo ni agbaboolu ti o ti gba ami ayo wole ju ni Real Madrid, ise ni o.

324..

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Suarez ranse si Messi

image

Looto ni wipe Barca nilo Messi ni ano gan ni.

Bi Suarez se gba ami ayo keji wole bayi, o fi ranse si Messi ni.

O fi owo meweewa ranse si, o fi iyen so iye ti a ko si Messi leyin.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Ibon lori papa

image

Bi awon egbe agbaboolu Brumadinho ati Amantes da Bola se n gba boolu ni orile ede Brazil, adajo ifesewonse na, Gabriel Murta da’ra ninu ifesewonse na.

Yato si adajo boolu afesegba ti Murta je, olopa ni arakurin yi.

Bi ifesewonse na se n lo, alayo Amantes yen ba gba Murta, o tu fun ese kan, kini Murta se o? Ni o ba yo ibon lapo! =-o

Opelope awon ti won di mu, ko ba pa alayo yen danu o.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

E wo awon ti wo n beru Messi ni Barcelona

image

Nigba ti Suarez n ba awon atileyin Barcelona soro ni Los Angeles, omo kan wa ba Suarez, o so fun wipe Suarez ni ohun feran ju ni Barcelona nitori ohun ni alayo ti o dara ju ni agbaye.

Kini Suarez so? O so wipe Messi ni alayo to dangajia ju ni agbaye.

Hmmm! Neymar na so nkan to jo bayi nigba to won so wipe ohun ni o dangajia ju ni agbaye.

Se eru Messi n ba won ni tabi kini?

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Se Wenger ko ni ba aye bobo yi je bayi?

image

Alayo Costa Rica ati Arsenal yi, Joel Campbell, darapo mo Arsenal lati odun 2011.

Gbogbo wa la mo wipe bobo yi dara gan, pelu nkan ti o tie gba ni World Cup, omo nla ni.

Sugbon se Wenger ni ko fun ni okan to bale ni, tabi ko mo boolu EPL gba?

Abi se Giroud mo boolu gba ju u lo ni?

Kini o n sele gan.?

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Se Ribery le gba ipo re pada bayi nitori…

image

Douglas Costa, alayo Schakter tele ni Bayern fi ropo Ribery to f’arapa.

Pep Guardiola wa so wipe “Costa yi ma wa lara awon agbaboolu to n gba ipo re to dangajia ju ni agbaye ti won ba ma ka marun ni agbaye yi.”

Se looto?

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Okada Barcelona ti pada o

image

Jordi Alba ti setan lati koju Bayer Leverkusen bayi sugbon Adriano ko I ti le gba boolu fun won.

Ki won ma lala ti Messi rara.

Boya ni Chicharito ko ni fi Oju won han mabo bayi.