E wo Awon to n gba iwaju Barca bi ‘drug dealer’

image

Tattoo yi sa..

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Advertisements

Wolfsburg je Oju Arsenal

image

Heheehe! sebi awon atileyin Arsenal kan n so wipe Wenger ma gbe Julian Draxler ni…

Wolfsburg ti gbe o.. won ti fi ropo De Bruyne to darapo mo Man City.

Wenger Wenger… ijebu 1!.

MAN Utd ta danu

image

Bi CH14 se lo di Bayer Leverkusen niyen o..

Awon ti Man Utd sa n sonu..

Iru akoni moogba wo leyi bayi?

Ohun lo mo o… ko sa le dan eleyi wo ni Chelsea…

Mourinho wo aso Barcelona

image

Orile ede Spain, ilu Barcelona ni a bi omo Mourinho, Jose Mourinho Jr si.

Amule Fulham U16 na je atileyin Barca, o si fi eleyi han gidi ni.

Koda, Messi ni o feran ju, nitori re ni o se wo aso re ya aworan.

Abi ogbon Mou lati je ki omo re di amule Barca leyi?

Omo yi jo Mou o..

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Oriire nla fun Nigeria

image

Awon af’owo so boolu sinu apere wa, D’Tigers, lano bori Angola lati gba ife eye Afro Basket Tunisia 2015 fun igba akoko.

65-74 ni won fi je awon Angola ni iya yi. Nigeria ko fibe bere ijakadi ma daada sugbon bi won se gbe Oguchi wole bayi, gbogbo re yori si rere fun wa ni.

Oguchi na ni o wa pada gba ife eye aladani ju, ife eye meta ni o gba.

Nigeria ku oriire!

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and
http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Roma se eleya JUVENTUS

image

Laye won, won ko padanu ifesewonse meji ri ni ibere sa..

Igara won ti poju… Won ta Pirlo.. Tevez.. Vidal.. won ti ri abajade re bayi..

Won ra Cuadrado, won sin lo Litchsteiner ati Evra laarin.. Won sese bere ni..

Oya.. e je ki a ko o fun won..

*Music* Moku mogbe Modaran*Music*

*Music* Iya lo po to’yi*Music*

*Music* o koro ju ewuro *Music*

*Music* O gbona ko si story*Music* … *run*