Mourinho gbe ija Hazard.. Oga gidi!

image

A ma to ma gbo nipa awon alayo ti o fe ja fun Ballon d’Or bayi,  Mourinho si ti so oro kan bayi.

“Mo gba wipe Messi se daada to lati gba ife eye Ballon d’Or nitori o gba ife eye meta, o si de asikagba Copa America.

“Ronaldo se daada to sugbon ife eye ti ko gba yen ti ja danu

“Hazard lo dara ju ni gbogbo England ni sa to koja, o si gba ife eye, o ni eto lati wa Lara awon meta to ma ja fun ife na

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Advertisements

Mourinho bu iyawo Benitez yamayama

image

Iyawo Rafa gan n be bi oya.

Egbe agbaboolu meta ti Mourinho ti ko ni boolu ni Rafa na ti ko, iyen ko tumo si wipe ife n be laarin won.

Iyawo Benitez  so tele wipe nkan ti Mou ba je ni Real Madrid ni ohun ati oko ohun wa tun se.

Mou ba fun lesi “iya yen ko mo nkan ti o n se ohun rara, o ye ki o wa ounje gidi fun oko re je ni.

“Se owo mi lo ti gba ise Madrid ni, oko re lo ba Inter ti mo to je!

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Kilode ti Guardiola se fe darapo mo Man City?

image

Awon oniroyin BEin ti n polongo wipe Pep Guardiola ti gba lati darapo mo Man City ni sa to n bo.

Idi gangan ni wipe o ibasepo ohun ati awon alayo re ti ni ifaseyin.

Jurgen Klopp ni o ma ropo re ni Igba na.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Madrid ta alayo ti Mourinho feran si Galatasaray

image

Galatasaray ti ra ololufe Mourinho Nigba to wa ni Real Madrid, Jose Rodriguez.

o yato si Jese Rodriguez o.. Boya nitori oruko kona ti ohun ati Mou n je ni o fi ni ife re=]y

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Neymar soro ija ohun ati Messi

image

O da bi wipe Neymar gan mo funra re wipe ohun na ma wa Lara awon ti won ma yan fun Ball on d’Or, awon oniroyin SporTv ni won wa bere wipe se o ni lokan lati gba Ballon d’Or ju Messi lo.

“Baba ni Messi, o de ti gba ife yi ni emerin otooto, mi ko ni lokan lati le Messi tabi lati gba ife yi ju Messi lo.

“Nkan ti o jemi logun ju ni bi mo se me dara ju ara mi nikan ni o.”

Oro gidi niyen.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Alayo Atletico Tuntun.

image

Atletico ti fi Jackson Martinez han agbaye bayi,awon atileyin won si ya boode lati wa ki i.

Kini Martinez gangan wa so?

“Lati Igba ti mo ti de, mo ri wipe egbe yi ni itara lati yege. Lowo yi, o damiloju wipe a ni nkan ti o to, ati nkan ti o ye lati koju Real Madrid ati Barcelona.”

Se looto ni?