Santi ati Theo mu inu Arsenal dun

Carzola ati Walcott ti se adehun tuntun pelu Arsenal bayi o..

O to si won!

Advertisements

O ma se o, ase Man Utd ko ti e ni’pon rara

image

PSG se Man Utd basu basu, apa won ja Man Utd ba je ba je.

Schwein ati Carrick ko lagbara awon to gba aarin fun PSG rara.

Blaise Matuidi ati Zlatan Ibrahimovic lo gba ami ayo meji wole fun PSG ti Man Utd ko si ri nkankan gba wole.

Bayi, PSG ni o gba ife eye na, Ibrahimovic si ni alayo to dangajia ju ni idije na.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Ibo ni Ibrahimovic ma ti gba boolu ni sa to n bo?

image

A bere lowo arakurin yi wipe ibo ni egbe agbaboolu ti o ma darapo mo leyin PSG, Ibrahim so wipe “iyalenu ni o ma je fun yin, e sa ma wo mi niran.”

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Ki’lo se Barca bayi?

image

Chelsea ko i ti ke da eyan na, leyin iya ti won je lowo NY Bulls, omi ni won fi ifesewonse meji lera gba sugbon won bori pelu penalty.

Barca ni tiwon, se nitori ko si Neymar ati Messi ni? ha! ami yen ko dara o

Hazard ni o koko fi eyin Barca se yeye na ni iseju mewa ti ifesewonse bere, Suarez ati Sandro wa dapada ki Masip to bun Cahill ni ami ayo.

Ami ayo merin si meji ni Chelsea fi bori penalty