Asise Chelsea lori Cech

Abolade Olajuwon Ryan

Chelsea so omo nu, Igba ti Cech wa ni ipo agbara amule gangan ni won wa ta a.

ki o to re amule daada, o ma n to ogoji ojo ori.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Advertisements

Kini Cech so fun Chelsea? Kini Mourinho so nipa re?

image

Abolade Olajuwon Ryan

E sa ti ta a danu? Nkan ti oju yin ba ri, ki e sa f’ara mo o.

Peteru Cech ti di alayo Arsenal bayi fun milionu mokanla pon, Mourinho si so wipe ti o ba Ku si ohun lowo ni, Cech koni kuro ni Chelsea.

“Mo be Abrahamovic lati je ki n si wa ni England nitori mo gbadun boolu ibi.

“Mo ro wipe mo si ma r’owo mu ni sugbon ko sele be, o dun mi wipe mi ko pari boolu si Chelsea, atileyin wa, e se gan o.”

Ese ti kika.

O ma se o! Kini Marcelo, Neymar ati Hulk n da lo bayi?

image

Abolade Olajuwon Ryan

Se Neymar nikan ni olugbala Brazil ni? Ti Neymar ko ba si lori papa, oran ni! Rara o, sebi won bori ifesewonse won siwaju iya ti Paraguay ko bo won.

Se ti Neymar ba wa nibe, igboya won ko ba ju bayi lo ni?

Tabi ki Neymar gan gba boolu lojo yen na, iya won ko ni koja lai kan won?

Ko n se nkan ti a mo awon ‘Selacao’ mo re e o. B’eyan kan ko gba boolu, igba to ma ropo re n be. Hmmm, o t’oju su mi, ibanuje okan si ni pelu.

Ese ti kika.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Shaqiri ya awon odo omode lenu bi arugbo.

image

Abolade Olajuwon Ryan

Xherden Shaqiri, alayo Bayern tele to n gba boolu jeun ni Inter Milan gba ipe lati ko awon odo omode Switzerland ni boolu sugbon ki o to bere, o tunra mu bi arugbo.

Nigba ti o bo si ori papa, ti ese re kan boolu, ti o n gba aramanda boolu wole, awon odo omode bere sini so wipe “kokoro kan n be ninu efo yi o, iru arugbo wo leyi?”

Ti Shaqiri yo irungbon lasan, inu won dun, won suru bo o ni.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Awon to koko gba boolu fun Nigeria re e o.

Abolade Olajuwon Ryan

Egbe agbaboolu Nigeria odun 1949 re o.

Lara awon alayo to wa nibe ni igba na ni Tesilimi ‘Thunder’ Balogun, Sam ‘The Black Magnet’ Ibiam , Etim Henshaw, Peter ‘Baby’ Anieke, Daniel Anyiam, ati Hope Lawson.

Ese ti kika.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Torres ja aso re gba pada.

image

Abolade Olajuwon Ryan

Ni Atletico, ti e ba n tele won daadaa tele, e ma mo wipe awon alagbara ni won ma n wo aso ti won ko mesan si leyin tele.

Forlan, Torres, Aguero, Villa ati beebelo.

Mandzukic ni o wo gbeyin, sugbon bi o se kuro yi, Torres sare gba a ni mi Martinez to de lati Porto.