Nkan to ma n sele si awon to ba padanu s’owo Juve

image

Ti Juve ba k’egba bo e, egbe agbaboolu re na ma k’egba bo e ni.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Advertisements

Scholes salaye iranu Di Maria

image

Abolade Olajuwon Ryan

Scholes, alayo Man Utd tele to n ko’we fun awon oniroyin ‘the Independent’ lo so bayi wipe “ti a ba wo iye ti Man Utd san fun Di Maria, ati wipe ohun ni alayo to dara ju ni Champions League sa to koja, osi ati iranu ni o gba fun Man Utd ni sa kini re, sibe sibe, mo ma gba Man Utd n’imoran wipe ki won ma ta a nitori o si wa lara re daada ni.”

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Falcao ni Chelsea

image

Abolade Olajuwon Ryan

Gbogbo wa la mo wipe Mourinho mo awon alayo kan ji ti won ba ti sun, a si mo wipe ati aye Atletico ni Mourinho ti fe ra Radamel Falcao.

Awon oniroyin ‘ Gianluca di Marzio’ wa so fun wa bayi wipe Chelsea fe ra arakurin na.

Hmmm! ko ya tete kuro ni Man Utd o.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Ibanuje Bravo lori Valdes ni Barcelona

image

Abolade Olajuwon Ryan

Claudio Bravo, amule Barcelona so wipe ohun ko feran oro ti awon atileyin Barcelona n so wipe o ti rope V.V, wipe ibanuje okan lo je f’ohun latari wipe ohun ko wa ropo enikeni o.

Eyin ti Barca, se looto ni wipe Bravo ti je ki e gbagbe Valdes?

Ese ti kika.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Benitez …. Osu to n bo.

image

Abolade Olajuwon Ryan

Nitori igbaradi fun sa tuntun ti Madrid ma gba ni Australia ati China ni osu keje odun yi, Real Madrid ti setan lati tete gbe ise fun Rafa Benitez .

Ojo keta osu to n bo ni Madrid ma fi Benitez  han.

Perez ati Benitez  ti n s’eto lati je ki adehun na sele kiakia.

Pelu iriri ti Rafa ti ni ni Liverpool, Inter, Chelsea, Napoli, ko ni si wahala pelu wipe onise kara kara ni Benitez .

Ese ti kika.

BBM : 534E8D29
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan si wa ni sportsinyoruba@gmail.com.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa ni
http://www.facebook.com/sportbouquet and http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Benitez fun Babel l’esi

image

Abolade Olajuwon Ryan

Leyin oro ti Babel fi tasi akoni moogba re tele wipe o ma so Ronaldo di eni to n gba eyin, Benitez  ti fun l’esi wipe “Napoli ti mo wa bayi, iwaju sa ni awon alayo mi n gba, sa sa ni eni ti o n gba Eyin.

“Iru alayo ti o ba n be lowo mi ni mo ma a fi sise.”

Benitez  ko lo igo oju re ninu aworan yi.=-d