Figo…aare FIFA tuntun! Mourinho


Abolade Olajuwon Ryan

Aremo orile ede Jordan, Ali Bin Al-Hussein la ro wipe o fe gba ijoko lowo Sepp Blatter bi i aare FIFA sugbon, opon ti sun o, alayo Barcelona ati Real Madrid tele, to gba boolu fun Portugal, Luis Figo ni opa ase kan bayi o. Mourinho si ti ki enu bo o.

Aaro ojoru ni Figo fi ero inu re han lati di aare FIFA, o si fe se eleyi lati “tun oruko FIFA to nitori won ti ba oruko yen je gidi gan.”

Mou to je omo orile ede re na ti gbe leyin re, o ni “Luis Figo mo nipa boolu gan, ohun ni o si le tun aajo FIFA to.

“Oniwa gidi ni, o si ni ipinu gan. O damiloju wipe ijoba re ma toro gan, o si ma se ise re bi ise.”

Se e faramo Figo bi i aare FIFA ti won ma dibo re ni osu karun odun yi?

BBM : 28A99F82
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan siwa ni
sportsinyoruba@gmail.com.
iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa lori http://
http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s