Bayern Munich ti gba Bundesliga


11bayern1_1368295396_540x540Abolade Olajuwon Ryan

Lowo yi, hmmm.. ki lo n sele ni Bundesliga? Bawo ni aye won se wa ri bayi? o ma se o… Afi Bayern yi i sa. Eni ti o so wipe ohun ma di gege siwon lorun, koda o so wipe ohun ma di Mourinho si Guardiola lorun, Jurgen Klopp gbinyanju sugbon ko ri nkan se si ni sa to koja, sa yi gan, ti Dortmund ba ni anfani lati lo si Champions League, iyalenu lo ma je nitori awon lo n rupo ni tabili Bundesliga bayi.

Eni to ye ki o gba won le ni won ta si Bayern Munich, iyen Mario GOTZE. Lewandowski si ti tele bayi. Rudi Voller to je adari Bayer Leverkusen gan ti so bayi wipe “odun 2000 ni a ma n gbiyanju lati fun Bayern ni wahala sugbon lowo yi, mi ko ri egbe ti o ke fun won ni wahala kankan o.

‘Gbogbo nkan won lo leto, awon to n ba won wa alayo na si n se ise won bi o ti ye.”

Bayer Leverkusen si lo wa ni ipo keta Bundesliga bayi, koko ami metadinlogun ni Bayern fi n lawon. (bi e se lanu ni emi na se lanu o).

Wolfburg to wa ni ipo keji gan, koko ami mokanla ni Bayern fi n siwaju re. Bayern ati Guardiola gangan ni won fi owo ba aye Dortmund je. Dorrtmund to le fun won ni wahala ni Bayern fi owo ra awon alayo to se koko ju ninu won. Ti Dortmund gan ko ba sora, ki won si na owo daadaa, tabi ki Rues wa kuro lodo won, afaimo ki won ma jakule si Bundesliga 2 o.

Ese ti kika.

BBM : 28A99F82
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan siwa ni
sportsinyoruba@gmail.com.
iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa lori http://
http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s