Anfani lati je airtime lori sportsinyoruba. kini abajade Chelsea ati Man City ma jasi?

Abolade Olajuwon Ryan

Airtime 200 ni a ma fun eni t’o ba gba idahun yi daadaa.

Ilano – E jowo, eni ti o ba koko gba a ni a ma fun o.

E fi idahun yin ati nomba tabi email yin si ibi ‘comment’ wa ni isale iroyin yi.

E jowo, e ma fi idahun otooto dahun si ibere wa.

O seese ki idahun yin ma tete han bi e ba se ko nitori wordpress ma se atejise si’wa lati ri wipe ilano to ye le tele. Eyin e sa dahun, awa ma fi han to ba ya.

Ejowo, e fi nomba yi le si egbe idahun yin.

Ese gan.

BBM : 28A99F82
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan siwa ni
sportsinyoruba@gmail.com.
iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa lori http://
http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Advertisements

Won na Bayern pa o!

Abolade Olajuwon Ryan

Wolfburg na Bayern pa lano ni Bundesliga. Bast ati Kevin de Bruyne lo gba ami ayo meji meji wole ti Bernat fi gba ami ayo kan soso wole.

Wolfburg ni egbe akoko to ma fi oju Bayern gbo’le ni sa yi, nkan ti won fi ki won kaabo si Bundesliga niyen.

Ami ayo merin si okan ni Wolfburg na won.

Oga gan o.. Sa yi ma le gan!

Ese ti kika.

BBM : 28A99F82
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan siwa ni
sportsinyoruba@gmail.com.
iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa lori http://
http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Asiri Messi to ti enu Neymar jabo!

Abolade Olajuwon Ryan

Ti a ba wo Neymar bayi, a ma ri wipe o ti yato gidi gan si Neymar sa to koja, omo na ti dagba ninu emi. Oro Messi ni o ku fun lati ma so bayi kaakiri adugbo.

O koko so wipe “mo n gbadun ara mi gidi gan ni, mi ko gbadun boolu ri bayi laye mi, mi ko mo baya mo ma gbadun re ju bayi lo sugbon mo n sa gbogbo agbara mi lati di alayo to dangajia si lojoojumo ni.

“Ise mi si po ni Barca baje baje, emi na mo wipe mo ti dara ju sa to koja lo. Ireti mi ni lati wa ninu iwe iranti Barca, ki n si gba ife eye repete fun won.

“Se e wa ri Messi ehn, ibi to ba wu ni ki won fi i si lori papa, nkan ti o ko wu emi ni wipe ko wa lori papa pelu mi, arakurin yen ti dangajia ju.

“Asiri irepo lori papa laarin emi ati Messi ni bo se je o, ore niwa gidi gan, a ma jo n jade daadaa, ti eleyi ba si wa, gbogbo nkan gbodo yori si rere lori papa laarin wa bi e se n ri yen.”

Ese ti kika.

BBM : 28A99F82
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan siwa ni
sportsinyoruba@gmail.com.
iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa lori http://
http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Ha!..Igbese nla ti Madrid ni fun Zidane ni wipe…

Abolade Olajuwon Ryan

Real Madrid je egbe kan to feran Zinedine Zidane gidi gan ni, won ma n ke bi eyin ni, won fe le ma ba Zidane je gidi gan nitori ko si nkan ti o fe ti won ki i fun. Kini o fe lote yi?

Florentino Perez, aare Real Madrid gangan lo feran Zidane ju, nigbati Zidane fe kuro ni Madrid ni sa to koja, ohun lo be e gidi gan, ti o si gbe ise Castilla le lowo. Perez ni igbagbo ninu Zidane gidi gan, to je wipe nigba ti Castilla wa ni isale tabili, Perez ni ki won farabale nitori ohun ni igbagbo ninu Zidane. Castilla wa ni oke tente bayi, igbagbo yi yori si rere.

Nkan ti Madrid fe fun bayi ni wipe ki o pari eko akoni moogba re, ti Ancelotti ba si so wipe ilo ti ya, won fe ki Zidane gba opa ase lowo re, ki o di akoni moogba Real Madrid.

Nkan ti Zidane na fe re e.

Se Zidane ma se daadaa bi akoni moogba Real Madrid sa?

Ese ti kika.

BBM : 28A99F82
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan siwa ni
sportsinyoruba@gmail.com.
iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa lori http://
http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Oro buruku ti Messi so fun Luis Enrique

Abolade Olajuwon Ryan

Sebi awa so fun yin wipe gobe sele ni Barcelona, wipe ko si irepo laarin Messi ati Luis Enrique. Mo so wipe oka ma fo, wipe a ma to ri fur* adiye.

Gbogbo oro ti Bartomeu ati Enrique n so fun wa wipe ko si gobe kankan, oro ife ni o, iro bansa!

Mathieu Jeremy, alayo Barcelona lo ba awon elero amititi orile ede France, RMC, wipe “igba ti a de lati isinmi ni gobe sele.

Ni Messi ba gbagbe ara re, bi a se n gbaradi, ni o ye ki won fun fere fun Messi fun ika ti won se e fun, Enrique ko si fun fere fun boolu na.

“Ni gobe ba sele, Messi ba so oro buruku si Enrique, o binu so awon oro won yi ni, Enrique ko lati dake fun, awon mejeeji ba wo’nu ija oro.

“Sugbon, ko ye ki oro na fa wahala to yen, awon oniroyin lo gbe gbigbona ju. Nitori a si je Barca ni oro na je be, awon eyan ma n karamo gbogbo nkan ti a ba se, won ko reti iwa buruku lati odo wa rara.”

Ese ti kika.

BBM : 28A99F82
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan siwa ni
sportsinyoruba@gmail.com.
iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa lori http://
http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Se ijiya Ika Ronaldo kere?

Abolade Olajuwon Ryan

To ba je wipe Suarez lo se ika fun Edimar, eyi ti Ronaldo se, se ifesewonse meji pere na ni won ma fi ofin di i fun?

Abi won ma ni ki o ma gba boolu mo gan ni laye laye. Se ijiya Ronaldo yi kere ju fun iwa to wu lori papa?

Ese ti kika.

BBM : 28A99F82
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan siwa ni
sportsinyoruba@gmail.com.
iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa lori http://
http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Figo…aare FIFA tuntun! Mourinho

Abolade Olajuwon Ryan

Aremo orile ede Jordan, Ali Bin Al-Hussein la ro wipe o fe gba ijoko lowo Sepp Blatter bi i aare FIFA sugbon, opon ti sun o, alayo Barcelona ati Real Madrid tele, to gba boolu fun Portugal, Luis Figo ni opa ase kan bayi o. Mourinho si ti ki enu bo o.

Aaro ojoru ni Figo fi ero inu re han lati di aare FIFA, o si fe se eleyi lati “tun oruko FIFA to nitori won ti ba oruko yen je gidi gan.”

Mou to je omo orile ede re na ti gbe leyin re, o ni “Luis Figo mo nipa boolu gan, ohun ni o si le tun aajo FIFA to.

“Oniwa gidi ni, o si ni ipinu gan. O damiloju wipe ijoba re ma toro gan, o si ma se ise re bi ise.”

Se e faramo Figo bi i aare FIFA ti won ma dibo re ni osu karun odun yi?

BBM : 28A99F82
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan siwa ni
sportsinyoruba@gmail.com.
iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa lori http://
http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Omo Real Madrid tuntun pelu Messi…Gobe!!!

Abolade Olajuwon Ryan

Leyin igba ti Real Madrid na Bayern Munich, Borussia Dortmund, Barcelona, Arsenal, Liverpool ati Ajax lati ra Odegaard, omo to n lo ese mejeeji re gba boolu yi ti di afiwe fun Messi.

Se won fe ba aye bobo yi je ni, omo odun melo ni ti won fi n we Messi? Ti won ba so wipe Messsi ni ojo iwaju o, iyen si dara. Sugbon wipe won n fi we Messi bayi, ha! Ki oro yi ma lo wo arakurin na lori o.

Odegaard to so wipe “ala mi di mimuse lati darapo mo Madrid ati wipe inu mi dun lati wa labe Zidane ni Castilla’ ni nkankan pelu Messi. Nkan yen si ni wipe baba awon mejeeji ma n polongo won fun araye ni i.

Alayo orile ede Norway tele Jan Aage Fjortoft so fun awon oniroyin Goal wipe “isokuso ni awon ti won n fi Messi we Martin n so, looto ni wipe Martin le se to Messi to ba dagba sugbon ki won ma fi we e bayi.

“Sibe sibe na, gbogbo nkan ti wo n so ko ti e wo Odegaard lori, omo na n se tie ni ati wipe nkan i wo n so ma pada di mimuse. Igba ti Kroos, Lham ati Schweinsteiger na kere, won soro nipa won, nkan ton sele bayi niyi.

“Nkan ti o ma se Odegaard ni anfani ju ni Zidane ti o ma ko o ni boolu, inu mi dun gidi gan, ese re a tu fi mo boolu daadaa ni.”

Ese ti kika.

BBM : 28A99F82
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan siwa ni
sportsinyoruba@gmail.com.
iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa lori http://
http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Iya ti won fi je Ronaldo ni wipe…

Abolade Olajuwon Ryan

Fun ika ti Ronaldo se ni opin ose yi fun Edimar, alayo Cordoba, awon igbinmo LFP ti pawopo lati fi iya to ye je Cristiano.

Won ko ni ki o san owo kankan o, sugbon won fi ofin di lati gba ifesewonse La liga meji to n bo. Ko ni koju ija si Sevilla ati Real Sociedad to na Madrid pa ni ibere sa yi pelu ami ayo merin si meji.

Ipadabo Ronaldo ma jasi igba ti won ma koju ija si Atl├ętico Madrid.

Ese ti kika.

BBM : 28A99F82
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan siwa ni
sportsinyoruba@gmail.com.
iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa lori http://
http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba

BBM : 28A99F82
BBM Channel: http://pin.bbm.com/C003889C7
Fun ipolowo ofe, e le kan siwa ni
sportsinyoruba@gmail.com.
iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, e ma gbagbe lati feran wa lori http://
http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba

Bayern Munich ti gba Bundesliga

11bayern1_1368295396_540x540Abolade Olajuwon Ryan

Lowo yi, hmmm.. ki lo n sele ni Bundesliga? Bawo ni aye won se wa ri bayi? o ma se o… Afi Bayern yi i sa. Eni ti o so wipe ohun ma di gege siwon lorun, koda o so wipe ohun ma di Mourinho si Guardiola lorun, Jurgen Klopp gbinyanju sugbon ko ri nkan se si ni sa to koja, sa yi gan, ti Dortmund ba ni anfani lati lo si Champions League, iyalenu lo ma je nitori awon lo n rupo ni tabili Bundesliga bayi.

Eni to ye ki o gba won le ni won ta si Bayern Munich, iyen Mario GOTZE. Lewandowski si ti tele bayi. Rudi Voller to je adari Bayer Leverkusen gan ti so bayi wipe “odun 2000 ni a ma n gbiyanju lati fun Bayern ni wahala sugbon lowo yi, mi ko ri egbe ti o ke fun won ni wahala kankan o.

‘Gbogbo nkan won lo leto, awon to n ba won wa alayo na si n se ise won bi o ti ye.”

Bayer Leverkusen si lo wa ni ipo keta Bundesliga bayi, koko ami metadinlogun ni Bayern fi n lawon. (bi e se lanu ni emi na se lanu o).

Wolfburg to wa ni ipo keji gan, koko ami mokanla ni Bayern fi n siwaju re. Bayern ati Guardiola gangan ni won fi owo ba aye Dortmund je. Dorrtmund to le fun won ni wahala ni Bayern fi owo ra awon alayo to se koko ju ninu won. Ti Dortmund gan ko ba sora, ki won si na owo daadaa, tabi ki Rues wa kuro lodo won, afaimo ki won ma jakule si Bundesliga 2 o.