Chicharito ni Real Madrid

Abolade Olajuwon Ryan

Iroyin to n lo ni England bayi ni wipe eni ti Man Utd fe le danu, Javier Hernandez to fe kuro ni Juventus ati Valencia n wa.

Eduardo Hernandez ti o je asojueni re ko ri adehun to boju mu pelu awon egbe won yi.

‘Dailymail’ ni o wa fi ye wa nisin wipe Real Madrid ma ra ogbeni na ti won ko ba ri Negredo tabi Falcao ra.

Awon oniroyin Marca wa so wipe alayo bi Chicharito ni Madrid nilo lati le ran Benzema lowo ni ipo re. Won ko nilo eni ti o ma ba Benzema fa wahala ju.

Ola, ojo aje ni ojo oja ma dopin ni won se tete n wa alayo kiakia.

Ese ti kika.

iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, ema gbagbe lati feran wa lori http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba.
Fun ipolowo ofe e le kan siwa ni sportsinyoruba@gmail.com. e ku ife.

Advertisements

Man Utd le Chicharito danu

Abolade Olajuwon Ryan

Ni osu kini odun yi, Manchester United fe ta Chicharito ni milionu mokandinlogun (19m) sugbon won tun yi okan won pada nipa omo orile ede Mexico na.

Alex Ferguson ra ogbeni ogbeni na ni odun 2010, awon atileyin Man Utd si tete ni ife re.

Bi David Moyes se de bayi, o di wahala fun un lati gba boolu ni.

Olori Man Utd, Ed Woodword wa yoju si Javier ni ojobo ose yi lati so fun wipe awon ko nilo ise re ni Man Utd mo o, wipe ki o ko eru re lo.

Won ni UEFA ma tilekun abawole oja ni ojo aje ose to n bo, wipe ki o wa egbe agbaboolu kan funra re ati wipe awon ma san gbogbo owo to wa ninu adehun re pelu Man Utd lati sa le je ki o ko eru re lo.

Ese ti kika.

iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, ema gbagbe lati feran wa lori http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba.
Fun ipolowo ofe e le kan siwa ni sportsinyoruba@gmail.com. e ku ife.

Chelsea gba ami ayo mefa wole loni

Abolade Olajuwon Ryan

Eto’o doju ko egbe ti o ba gba boolu ni sa to koja, Chelsea sugbon iya lo ba nibe.

Ayo mefa si meta ni Chelsea fi ko iya fun Everton sugbon ifesewonse na dun gan nitori Everton ko gba fun Chelsea rara.

Costa, omo orile ede Spain ti a bi si Brazil ni o gba ami ayo meji wole, ti Ivanovic, Matic, Ramires ati omo Everton na to gba amiayo wole ara re.

Moses ba Stoke City na Man City ni ayo kan si odo, Man Utd ni tiwon tesiwaju ninu iranu ti won gba.

Van Gaal sa so wipe ki n ma ni suru fun ohun.

Awon ifesewonse to ku to waye re o.

Burnley 0 – 0 Manchester United
FT Manchester City 0 – 1 Stoke City
FT Newcastle United 3 – 3 Crystal Palace
FT Queens Park Rangers 1 – 0 Sunderland
FT Swansea City 3 – 0 West Bromwich Albio
FT West Ham United 1 – 3 Southampton
FT Everton 3 – 6 Chelsea

Ese ti kika.

iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, ema gbagbe lati feran wa lori http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba.
Fun ipolowo ofe e le kan siwa ni sportsinyoruba@gmail.com. e ku ife.

Ronaldo kilo fun Di Maria wipe

Abolade Olajuwon Ryan

Sportsinyoruba so fun yin tele wipe aso ti won ko meje si leyin(ti Di Maria n wo ni Argentina) ni Di Maria ma wo ni Man Utd.

Awon alayo jankan jankan lo ma n wo aso na, ti won ba si sise kara kara, ogo aso yen ma n yo.

David Beckham ati Ronaldo gbe aso yi wo, won si se daadaa pelu, Nani wo sugbon o gbe jule pada ni. Idi ti Ronaldo se kllo fun Di Maria niyen wipe “ise nla ni fun eni ti o ba ma wo aso yi o”.

Ronaldo wa so wipe “mo mo Di Maria dara dara, alayo to dangajia gidi gidi gan ni. O ma le se ise ti o ma gbe ogo aso yi yo.

“Mo ma saro Di Maria gan nitori mo feran isesi gba boolu re.

Leyin Cristiano Ronaldo, ko si eni to wo aso yen to se dara dara ri sugbon Di Maria ti pinu lati “se bi Ronaldo fun Man Utd.

Ese ti kika.

iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, ema gbagbe lati feran wa lori http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba.
Fun ipolowo ofe e le kan siwa ni sportsinyoruba@gmail.com. e ku ife.

Ronaldo – Mo feran Messi

Abolade Olajuwon Ryan

Fun bi odun mefa seyin, ija orogun fun oba boolu afesegba wa laarin Cristiano ati Lionel.

Ronaldo omo Madrid ni awon oniroyin wa n ba soro ti o fi so wipe “ija orogun emi ati Messi ko sese bere o, ati igba ti mo ti wa ni Manchester United ni.

Awon oniroyin ma n fiwan we ara won, awon kan ma so wipe ikan ko mo boolu gba rara, awon atileyin boolu won na ma n so tiwan. Koda awon atileyin omiran ma n ja ni.

Esi ti Ronaldo fun won ni wipe “dandan ni ki won fi wa we ara wa nitori awa mejeeji n se ise kara kara fun egbe agbaboolu wa ni, awon atileyin wa lo ma n gbadun boolu gan.

“Mo feran orogun to wa laarin emi ati Messi, akosile ni, mo de gbadun re gan. Nkan ti o n je ki a dara si niyen. Mo feran Messi bi agbaboolu egbe mi ni, ibe na lo tan si” ni Ronaldo fi pari oro re.

Ese ti kika.

iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, ema gbagbe lati feran wa lori http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba.
Fun ipolowo ofe e le kan siwa ni sportsinyoruba@gmail.com. e ku ife.

Barca fun Westham ni Song

Abolade Olajuwon Ryan

Milionu meedogun ni Arsenal ta Song fun Barcelona lati dipo Keita sugbon arakurin na ko ri boolu gba dara dara.

Lati 2012 yen gan, awon eyan kan bu ogbeni na wipe o si egbe paro ni, wipe ko ba ma lo si Barca.

Galatasaray fe ra ogbeni na lo si Turkey sugbon Song ko fe lo si ilu yen, o ko adehun na.

Westham ti wa be Barca ki won ya awon ni Song fun odun kan pere nitori won fe ta Mohamed Diame.

Song ma wa danikan gun oko ofurufu lo si England bayi lati se ayewo pelu awon dokita Westham ki o to darapo mo won.

Ese ti kika.

iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, ema gbagbe lati feran wa lori http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba.
Fun ipolowo ofe e le kan siwa ni sportsinyoruba@gmail.com. e ku ife.

Van Gaal – Man Utd si ma je iya pelu Di Maria

Abolade Olajuwon Ryan

Di Maria ma koju ija ti Burnley ni ojo oni pelu Manchester United. Van Gaal, akoni moogba Man Utd ti so wipe Di Maria nikan ko to lati din iya Man Utd ku.

Van Gaal wa so wipe ohun fe bowo fun Moyes ati Ferguson, ohun ko ni da won lebi fun iru awon alayo ti won file fun ohun.

“Ojo meji pere ni Di Maria ti gbaradi pelu Man Utd, iyen ko to lati din iya ti Man Utd n je ku. O si ma nilo ati mo owo awon alayo egbe re, awon iyen na si gbodo mo owo re.

“Sugbon bo pe boya o, iya yi ma din ku lojo kan.

Van Gaal ti toro osu meta lati so Man Utd di bi araye se mo won tele.

Man Utd ko si ti i jawe olubori kankan ni sa yi.

Ese ti kika.

iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, ema gbagbe lati feran wa lori http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba.
Fun ipolowo ofe e le kan siwa ni sportsinyoruba@gmail.com. e ku ife.

Everton-Lille, Tottenham-Besiktas ni Europa League

Abolade Olajuwon Ryan

A ti se ipin fun awon egbe mejidinlaadota (48) ti won ma gba Europa League odun yi.

Benitez to gba pelu Chelsea ni odun meji seyin ma dari Napoli ni odun yi latari iya ti Athletic Bilbao fi ja won ni Champions League ni ijeta.

Egbe mejila ni a pin gbogbo won si bayi –

Villarreal
Borussia
Monchengladbacj
Zurich
Apollon

Copenhagen
Club Brugge
Torino
HJK Helsinki

Tottenham
Besiktas
Partizan
Asteras

Salzburg
Celtic
Dinamo Zagreb
Astra

PSV
Panathinaikos
Estoril
Dinamo Moscow

Inter
Dnipro
Saint-Etienne
Qarabag

Sevilla
Standard Liege
Feyenoord
Rijeka

Lille
Wolfsburg
Everton
Krasnodar

Napoli
Sparta Prague
Young Boys
Slovan Bratislava

Dynamo Kyiv
Steaua Bucharest
Rio Ave
Aab Aalborg

Fiorentina
PAOK
Guingamp
Dinamo Minsk

Metalist
Trabzonspor
Legia
Lokeren

Bi a se pin won re e o.

Ese ti kika.

iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, ema gbagbe lati feran wa lori http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba.
Fun ipolowo ofe e le kan siwa ni sportsinyoruba@gmail.com. e ku ife.

Torres dipo Balotelli ni AC Milan.

Abolade Olajuwon Ryan

Mourinho so wipe ohun nilo alayo ti o ma gba iwaju meta (Costa, Torres ati Drogba), o da bi wipe Torres ko si laarin won mo o.

“Milan ati Chelsea ti se adehun lati ran ogbeni na lo si Milan titi di 2016” ni Chelsea so.

Lati igba ti Chelsea ti ra Torres lati Liverpool fun aadota milionu pon (50m), ko gbe ise owo re yo, Mourinho ko si fe lo o mo.

Owo osu Torres ni o fe fa idiwo fun adehun na sugbon awon egbe mejeeji yi ti san owo laarin arawon.

Torres dipo Balotelli to sese lo si Liverpool, a tu darapo mo Essien ni Milan na.

Mourinho si ma wa alayo to ma dipo re bayi.

Ese ti kika.

iwe iroyin wa n bo layipe.
E jowo, ema gbagbe lati feran wa lori http://www.facebook.com/sportsinyoruba ati http://www.twitter.com/sportsinyoruba.
Fun ipolowo ofe e le kan siwa ni sportsinyoruba@gmail.com. e ku ife.

Baba Di Maria jewo ija laarin Madrid ati Di Maria

Abolade Olajuwon Ryan

Ni sa to koja, baba Ozil ati Real Madrid ni won jo ni ija nitori adehun ti won fe ba omo re se ati wipe won ta a si Arsenal.

Baba Di Maria lo wa so idi ti omo re se kuro gangan ni Madrid lo si Man Utd.

“Di Maria ni ifokanbale ni Man Utd, won mo iyi re, won si n wuwa rere si i. Sugbon ni Madrid yen, gbogbo igba ni Madrid fe ki o fi ara re han. Omo mi ti se eleyi ni aimoye igba sugbon won ko mo iyi re na.

Nkan ti Higuain na so ni sa to koja niyen.

Nipa oro owo gangan, milionu mefa ni a gbo wipe Madrid fe fun Di Maria ti o si ko sile sugbon baba re ni “milionu meta ati abo ni omo mi n gba tele, leyin World Cup, won fe fi milionu kan ati abo kun.

“Ko n se milionu mefa ni won fi lo wa o, milionu marun pere ni. Man Utd si wa fun un ni owo to ju be lo.

Di Maria so fun mi loni wipe owo ti ohun bere yen ko po ju. Se ooto ni?